Talebale lyrics - Jaymikee

 
Talebale lyrics


A jẹ' bí ọmọdé tí ìyá rẹ rán lọ s'ọjà
Ah ah ah ah ah ah
Ọjà ilé ayé láti ra láti tá
Ah ah ah ah ah ah
Ṣùgbọ'n tí ilẹ' bá bẹ'rẹ' si ní ń ṣú
Tí òkùnkùn bá bo 'lẹ'
Ti oníkálukú bá pá lẹ ọjà mọ
Ma jẹ' kí ń gbàgbé láti kọ 'ri si 'lè


Jésù ó jọ'wọ' ó má má jẹ' ń kùnà
Kíi má bá ṣ' ègbé ló ṣe kú fún mi
Jésù ó jọ'wọ' ó má má jẹ' n ṣìnà
Kíi má bá ṣ' ègbé ló ṣe kú fún mi
Nígbà t'álẹ' bá lẹ'
T'ọjà ayé tú
Jẹ' kí n r' ọkọ rẹ bá relé
Nígbà t'álẹ' bá lẹ'
T'ọjà ayé tú
Jẹ' kí n r' ọkọ rẹ bá relé


Ìjọba ọrùn dá bí àwọn wúńdíá mẹ'wàá
Ah ah ah ah ah ah ah
Tí wọn mú fìtílà wọn lọ pàdé ọkọ ìyàwó
Ah ah ah ah ah ah ah
Elédùmarè má má jẹ' kí n dí alaigbagbọn
Fún mi ní ọgbọ'n bí àwọn wúńdíá ọlọ'gbọ'n
Kólóbó mì rèé ó
Rọ' kún pẹ'lú òróró rẹ
Kíi n fí dúró dé ọ'


Jésù ó jọ'wọ' ó má má jẹ' ń kùnà
Kíi má bá ṣ' ègbé ló ṣe kú fún mi
Jésù ó jọ'wọ' ó má má jẹ' n ṣìnà
Kíi má bá ṣ' ègbé ló ṣe kú fún mi
Nígbà t'álẹ' bá lẹ'
T'ọjà ayé tú
Jẹ' kí n r' ọkọ rẹ bá relé
Nígbà t'álẹ' bá lẹ'
T'ọjà ayé tú
Jẹ' kí n r' ọkọ rẹ bá relé


Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé
Mú Mí délé ó ó Mú mi délé


Jésù ó jọ'wọ' ó má má jẹ' ń kùnà
Kíi má bá ṣ' ègbé ló ṣe kú fún mi
Bàbá jọ'wọ' ó má má jẹ' n ṣìnà
Kíi má bá ṣ' ègbé ló ṣe kú fún mi
Nígbà t'álẹ' bá lẹ'
T'ọjà ayé tú
Jẹ' kí n r' ọkọ rẹ bá relé
Nígbà t'álẹ' bá lẹ'
T'ọjà ayé tú
Jẹ' kí n r' ọkọ rẹ bá relé
Baba Ah!



Post a Comment

0 Comments